Applications for Cohort 14 open soon Join the next cohort
← All courses

Online course

Script Writing Yoruba

Ìfihàn sí ìkọ̀wé eré fún pẹpẹ àti ojú-iboju. Ẹ̀kọ́ yìí máa jẹ́ kí o mọ díẹ̀ lára àwọn ọgbọ́n pàtàkì tó jẹ́ ìpìlẹ̀ fún ìkọ̀wé eré orí pẹpẹ: ìjíròrò, ohun kikọ, àti ìṣètò ìtàn.

9 Modules
36 Learning activities
Online Delivery
Script Writing Yoruba

Course curriculum

What you'll explore.

MODULE 01 Ìfáárà 3 activities
  1. Ẹ Káàbọ̀ sí Cohort 14 Text
  2. Ìdánwò Ṣáájú Ìkẹ́kọ̀ọ́ Survey
  3. Ẹ Káàbọ̀ Video
MODULE 02 Ẹ̀kọ́ 1 3 activities
  1. Ìfáárà: Ìrísí Eré àti Ọ̀nà Ìfihàn Rẹ̀ Video
  2. Ohun Èlò Akọ̀wé Video
  3. Pápá Ìjíròrò Text
MODULE 03 Ẹ̀kọ́ 2 3 activities
  1. Ẹ̀bùn Àbínibí àti Ọgbọ́n Iṣẹ́ Video
  2. Lílo Ìrònú Àwòrán Rẹ Nínú Ìkọ̀wé Eré Àtinúdá Video
  3. Yíyan Ọ̀nà Ìfihàn Video
MODULE 04 Ẹ̀kọ́ 3 5 activities
  1. Ìkọ̀wé Eré: Ìkọ̀wé Eré Orí Pẹpẹ àti Ìkọ̀wé Eré Ojú-Iboju Video
  2. Kíkọ Ìtàn Kúkúrú Video
  3. Kíkọ Eré Video
  4. Ìdánwò Ìmọ̀ Quiz
  5. Pápá Ìjíròrò Text
MODULE 05 Ẹ̀kọ́ 4 2 activities
  1. ÌTÀN: Ìṣètò Ìṣẹ̀lẹ̀ àti Ìṣètò Ìtàn Video
  2. Ìṣe Eré Video
MODULE 06 Ẹ̀kọ́ 5 8 activities
  1. Ṣíṣe Ìṣètò Ìṣẹ̀lẹ̀ Eré Video
  2. Àwọn Ọ̀nà Eré Nínú Kíkọ Ìṣètò Ìṣẹ̀lẹ̀ Video
  3. Ohun Kikọ Video
  4. Ìjíròrò Video
  5. Àyíká àti Àkókò Ìtàn Video
  6. Ìran Eré Video
  7. Ẹ̀ka Ìtàn àti Àwòṣe Ìpilẹ̀ Video
  8. Ìdánwò Ìmọ̀ Quiz
MODULE 07 Ẹ̀kọ́ 6 8 activities
  1. Bí Akọ̀wé Eré Ṣe Máa Ṣàfihàn Iṣẹ́ Rẹ̀ Fún Títà (Pitch) Video
  2. Gbolóhùn Àkótán (Logline) Video
  3. Àkótán Ìtàn àti Àlàyé Ìtàn (Synopsis & Treatment) Video
  4. Ìmúrasílẹ̀ Fún Ìpàdé Ìfihàn Iṣẹ́ Video
  5. Ṣíṣe Iṣẹ́ Rẹ Nípasẹ̀ Ara Rẹ Video
  6. Nẹ́tíwọ́ọ̀kì àti Ìdúnàádúrà Àdéhùn Video
  7. Títún Kọ àti Ṣíṣe Àtúnṣe Video
  8. Ìdánwò Ìmọ̀ Quiz
MODULE 08 Ẹ̀kọ́ 7 2 activities
  1. Ìrìnàjò Tí Kò Lópìn Video
  2. Ìdánwò Ìkẹyìn Quiz
MODULE 09 Ìgbésẹ̀ Tó Kàn 2 activities
  1. Ẹ Kú Oríire! Èyí ni Ìgbésẹ̀ Tó Kàn... Video
  2. Kí O Tó Lọ... Survey

Ready to begin?

Continue to the TAFTA LMS. This course will already be selected for your registration.

Enroll now ↗

Explore more

Find the path that moves you.

Browse TAFTA's other creative and professional learning programmes.

View all courses ↗